2 Sámúẹ́lì 23:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì dà bí ìmọ́lẹ̀ òwúrọ̀ nígbà tí oòrùn bá là,òwúrọ̀ tí kò ní ìkúukùu,nígbà tí koríko tútùbá hù wá láti ilẹ̀ lẹ́yìn òjò.’

2 Sámúẹ́lì 23

2 Sámúẹ́lì 23:1-9