2 Sámúẹ́lì 23:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nǹkan wọ̀nyí ní Banáyà ọmọ Jéhóíádà ṣe, ó sì ní orúkọ nínú àwọn ọkùnrin alágbára mẹ́ta náà.

2 Sámúẹ́lì 23

2 Sámúẹ́lì 23:19-31