2 Sámúẹ́lì 22:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èéfín sì jáde láti ihò-imú rẹ̀ wá;iná láti ẹnu rẹ̀ wá,ó sì ń jónirun, ẹ̀yín sì ń ràn nípasẹ rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:3-15