2 Sámúẹ́lì 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà tí ìbìlù ìrora ikú yí mi káàkiri;tí àwọn ìṣàn ènìyàn búburú dẹ́rùbà mí.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:1-13