2 Sámúẹ́lì 22:49 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti ẹni tí ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀ta mi.Ìwọ sì gbé mi sókè ju àwọn tí ó dìde sí mi lọ;ìwọ sì gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin oníwà ipá.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:42-51