2 Sámúẹ́lì 22:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ sì ti fi agbára dì mí ní àmùrè fún ìjà;àwọn tí ó ti dìde sí mi ni ìwọ sì ti tẹ̀ lórí ba fún mi.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:31-50