2 Sámúẹ́lì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run mi, àpáta mi, nínú ẹni tí èmi ní ààbò,àti ìwọ ìgbàlà mi, ibi ìsádi gíga mi,àti ibi ìlùmọ̀ mi, Olùgbàlà mi;ìwọ ni ó ti gbà mí kúrò lọ́wọ́ ìwà ipá.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:1-12