2 Sámúẹ́lì 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n wá láti borí mi lọ́jọ́ ìpọ́njú mi:ṣùgbọ́n Olúwa ni aláfẹ̀hìntì mi.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:17-27