2 Sámúẹ́lì 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìṣàn ibú òkun sì fi ara hàn,ìpìlẹ̀ ayé fi ara hàn,nípa ìbáwí Olúwa,nípa fífún èémí ihò imú rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 22

2 Sámúẹ́lì 22:8-21