2 Sámúẹ́lì 22:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Dáfídì sì kọ ọ̀rọ̀ orin yìí sí Olúwa ní ọjọ́ tí Olúwa gbà á kúrò lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀ta rẹ̀, àti kúrò lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.

2. Ó sì wí pé,“Olúwa ni àpáta mi, àti Olùgbàlà mi;

2 Sámúẹ́lì 22