2 Sámúẹ́lì 21:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ogun sì tún wà láàrin àwọn Fílístínì àti Ísírẹ́lì; Dáfídì sì sọ̀kalẹ̀, àti àwọn ìránṣẹ rẹ̀ pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bá àwọn Fílístínì jà: ó sì rẹ Dáfídì.

2 Sámúẹ́lì 21

2 Sámúẹ́lì 21:6-22