2 Sámúẹ́lì 21:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú egungun Sọ́ọ̀lù àti egungun Jónátánì ọmọ rẹ̀ láti ibẹ̀ náà wá; wọ́n sì kó egungun àwọn tí a ti so rọ̀ jọ.

2 Sámúẹ́lì 21

2 Sámúẹ́lì 21:11-22