2 Sámúẹ́lì 20:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámásà sì lọ láti pe àwọn ọkùnrin Júdà; ṣùgbọ́n ó sì dúró pẹ́ ju àkókò tí a fi fún un.

2 Sámúẹ́lì 20

2 Sámúẹ́lì 20:1-6