2 Sámúẹ́lì 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lákòókò yìí, Ábínérì ọmọ Nérì olórí ogun Ṣọ́ọ̀lù ti mú Íṣíbóṣétì ọmọ Ṣọ́ọ̀lù, ó sì mú un kọjá sí Máhánáímù.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:3-11