2 Sámúẹ́lì 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rán oníṣẹ́ sí àwọn ọkùnrin Jábésì Gílíádì láti sọ fún wọn pé, “Olúwa bùkún un yín fún fífi inú rere yín hàn sí Ṣọ́ọ̀lù ọ̀gá yín nípa sí sin ín.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:1-13