2 Sámúẹ́lì 2:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì àti àwọn ọmọkùnrin rẹ̀ sì fi gbogbo òru náà rìn ní pẹ̀tẹ́lẹ̀, wọ́n sì kọjá Jọ́dánì, wọ́n sì rìn ní gbogbo Bítírónì, wọ́n sì wá sí Mahanáímù.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:20-32