2 Sámúẹ́lì 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì wí pé, “Bí Ọlọ́run ti ń bẹ, bí kò ṣe bí ìwọ ti wí, nítòótọ́ ní òwúrọ̀ ni àwọn ènìyàn náà ìbá padà lẹ́yìn arákùnrin wọn.”

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:22-32