2 Sámúẹ́lì 2:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù àti Ábíṣáì sì lépa Ábínérì: òòrùn sì wọ̀, wọ́n sì dé òkè ti Ámímà tí o wà níwájú Gíà lọ́nà ijù Gíbíónì.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:22-29