2 Sámúẹ́lì 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábínérì bojú wo ẹ̀yìn rẹ̀, Ó sì béèrè pé, “Ṣé ìwọ Ásáhélì ni?”Ó dáhùn pé, “Bẹ́ẹ̀ ni,”

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:13-22