2 Sámúẹ́lì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ogun náà ní ọjọ́ náà gbóná. Àwọn ọmọkùnrin Dáfídì sì ṣẹ́gun Ábínérì pẹ̀lú àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì.

2 Sámúẹ́lì 2

2 Sámúẹ́lì 2:14-27