2 Sámúẹ́lì 19:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì ń lọ́ sí Gílígálì, Kímhámù sì ń bà a lọ, gbogbo àwọn ènìyàn Júdà sì ń ṣe ìkẹ́ ọba, àti ààbò àwọn ènìyàn Ísírẹ́lì.

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:37-43