2 Sámúẹ́lì 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì bo ojú rẹ̀, ọba sì kígbe ní ohùn rara pé, “Áì! Ọmọ mi Ábúsálómù! Ábúsálómù ọmọ mi, ọmọ mi!”

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:1-12