2 Sámúẹ́lì 19:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún Básíláì pé, “Ìwọ wá bá mi gòkè odò, èmi ó sì máa pésè fún ọ ní Jérúsálẹ́mù.”

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:24-41