2 Sámúẹ́lì 19:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Básíláì ará Gílíádì sì sọ̀kalẹ̀ láti Rogelímù wá, ó sì bá ọba gòkè odò Jódánì, láti ṣe ìkẹ́ rẹ̀ sí ìkọjá odò Jódánì.

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:24-33