2 Sámúẹ́lì 19:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣíméhì ọmọ Gérà, ará Bẹ́ńjámínì ti Báhúrímù, ó yára ó sì bá àwọn ọkùnrin Júdà sọ̀kalẹ̀ láti pàdé Dáfídì ọba.

2 Sámúẹ́lì 19

2 Sámúẹ́lì 19:11-21