2 Sámúẹ́lì 18:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ogun náà sì fọ́n káàkiri lórí gbogbo ilẹ̀ náà: igbó náà sì pa ọ̀pọ̀ ènìyàn ju èyí tí idà pa lọ lọ́jọ́ náà.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:2-13