2 Sámúẹ́lì 18:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì wò ó, Kúṣì sì wí pé, “Ìhìnrere fún Olúwa mi ọba: nítorí tí Olúwa ti gbẹ̀san rẹ lónìí lára gbogbo àwọn tí ó dìde sí ọ.”

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:23-33