2 Sámúẹ́lì 18:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Álóre náà sì kígbe, ó sì wí fún ọba.Ọba sì wí pé, “Bí ó bá ṣe òun nìkan ni, ìhìn rere ń bẹ lẹ́nu rẹ̀.” Òun sì ń súnmọ́ tòsí.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:20-28