2 Sámúẹ́lì 18:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóábù sì fun ìpè, àwọn ènìyàn náà sì yípadà láti máa lépa Ísírẹ́lì: nítorí Jóábù ti pe àwọn ènìyàn náà padà.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:15-21