2 Sámúẹ́lì 18:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá ṣe bẹ́ẹ̀ èmi ìbá ṣe sí ara mi: nítorí pé kò sí ọ̀ràn kan tí ó pamọ́ fún ọba, ìwọ tìkárarẹ̀ ìbá sì kọjú ìjà sí mi pẹ̀lú.”

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:12-18