2 Sámúẹ́lì 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkùnrin kan sì rí i, ó sì wí fún Jóábù pé, “Wò ó, èmi rí Ábúsálómù so rọ̀ láàrin igi óákù kan.”

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:8-14