2 Sámúẹ́lì 18:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sì ka àwọn ènìyàn tí ń bẹ lọ́dọ̀ rẹ̀, ó sì mú wọn jẹ balógun ẹgbẹgbẹ̀rún, àti balógun ọrọrún lórí wọn.

2 Sámúẹ́lì 18

2 Sámúẹ́lì 18:1-5