2 Sámúẹ́lì 17:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwá ó sì yọ sí i níbikíbi tí àwa o gbé rí i, àwa ó sì yí i ká bí ìrì ti ń ṣẹ̀ sí ilẹ̀ àní, ọkàn kan kì yóò kù pẹ̀lú rẹ̀ nínú gbogbo àwọn ọmọkùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 17

2 Sámúẹ́lì 17:11-20