2 Sámúẹ́lì 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábíṣáì ọmọ Serúià sì wí fún ọba pé, “Èéṣe tí òkú ajá yìí fi ń bú Olúwa mi ọba? Jẹ́ kí èmi kọjá, èmi bẹ̀ ọ́, kí èmi sì bẹ́ ẹ́ lórí.”

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:6-12