2 Sámúẹ́lì 16:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí pé, “Ọmọ olúwa rẹ dà?”Ṣíbà sì wí fún ọba pé, “Wò ó, ó jókòó ní Jérúsálẹ́mù; nítorí tí ó wí pé, ‘Lónìí ni ìdílé Ísírẹ́lì yóò mú ìjọba baba mi padà wá fún mi.’ ”

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:1-13