2 Sámúẹ́lì 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bóyá Ọlọ́run yóò wo ìpọ̀njú mi, Olúwa yóò sì fi ire san án fún mi ní ipò èébú rẹ̀ lónìí.”

2 Sámúẹ́lì 16

2 Sámúẹ́lì 16:6-22