2 Sámúẹ́lì 15:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ábúsálómù yóò sì wí fún un pé, “Wò ó, ọ̀ràn rẹ sá dára, ó sì tọ́: ṣùgbọ́n kò sí ẹnìkan tí ọba fi àṣẹ fún láti gbọ́ ọ̀ràn rẹ.”

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:1-7