2 Sámúẹ́lì 15:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sádókù àti Ábíátarì sì gbé àpótí-ẹ̀rí Ọlọ́run padà sí Jérúsálẹ́mù: wọ́n sì gbé ibẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:26-34