2 Sámúẹ́lì 15:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lánàá yìí ni ìwọ dé, èmi ó ha sì mú kí ìwọ máa bá wá lọ kákiri lónìí bí? Èmi ń lọ sí ibikíbi tí mo bá rí: padà, kí o sì mú àwọn arakùnrin rẹ padà, kí àánú àti òtítọ́ Olúwa wà pẹ̀lú rẹ.”

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:16-21