2 Sámúẹ́lì 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹnìkan sì wá rò fún Dáfídì pé, “Ọkàn àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì ṣí sí Ábúsálómù.”

2 Sámúẹ́lì 15

2 Sámúẹ́lì 15:5-18