2 Sámúẹ́lì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún Jóábù pé, “Wò ó, èmi ó ṣe nǹkan yìí: nítorí náà lọ, kí o sì mú ọmọdékùnrin náà Ábúsálómù padà wá.”

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:15-22