2 Sámúẹ́lì 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ìránṣẹ́bìnrin rẹ̀ sì wí pé, ‘Ǹjẹ́ ọ̀rọ̀ ọba Olúwa mi yóò sì jásí ìtùnú; nítorí bí ańgẹ́lì Ọlọ́run bẹ́ẹ̀ ni Olúwa mi ọba láti mọ rere àti búburú: Olúwa Ọlọ́run rẹ yóò sì wà pẹ̀lú rẹ.’ ”

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:8-18