2 Sámúẹ́lì 13:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún un pé, “Èéṣe tí ìwọ ọmọ ọba ń fi ń rù lójojúmọ́ báyìí? Ǹjẹ́ o kò ní sọ fún mi?”Ámúnónì sì wí fún un pé, “Èmi fẹ́ Támárì àbúrò Ábúsálómù arákùnrin mi.”

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:1-12