2 Sámúẹ́lì 13:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónádábù sì wí fún ọba pé, “Wò ó, àwọn ọmọ ọba ń bọ́; gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ ìránṣẹ́ rẹ̀, bẹ́ẹ̀ ni ó rí.”

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:31-36