2 Sámúẹ́lì 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì dìde, ó sì fa aṣọ rẹ̀ ya, ó sì dùbúlẹ̀ ni ilẹ̀; gbogbo àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ tí wọ́n dúró tì í sì fà aṣọ wọn ya.

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:21-34