2 Sámúẹ́lì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hánúnì sì mú àwọn ìránṣẹ Dáfídì ó fá apákan irungbọ̀n wọn, ó sì gé ààbọ̀ kúró ní agbádá wọn, títí ó fí dé ìdí wọn, ó sì rán wọn lọ.

2 Sámúẹ́lì 10

2 Sámúẹ́lì 10:1-9