2 Sámúẹ́lì 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nígbà náà ó wí fún mi pé, ‘Dúró lórí ì mi kí o sì pa mí! Èmi wà nínú ìrora ikú, ṣùgbọ́n mo wà láàyè.’

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:1-17