2 Sámúẹ́lì 1:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn mi gbọgbẹ́ fún ọ Jónátanì arákùnrin mi;ìwọ ṣọ̀wọ́n fún mi.Ìfẹ́ rẹ sí mi jẹ́ ìyanu,ó jẹ́ ìyanu ju ti obìnrin lọ.

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:22-27