2 Sámúẹ́lì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dáfídì sọ fún ọkùnrin tí ó mú ìròyìn wá fún un pé, “Níbo ni ó ti wá?”O dáhùn pé, “Ọmọ àlejò ni mo jẹ́, ará Ámálékì.”

2 Sámúẹ́lì 1

2 Sámúẹ́lì 1:5-20