2 Pétérù 3:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn ó sì máa wí pé, “Níbo ni ìlérí wíwà rẹ̀ gbé wà? Láti ìgbà tí àwọn baba ti sùn, ohun gbogbo ń lọ bí wọ́n ti wà rí láti ìgbà ọjọ́ yìí wá.”

2 Pétérù 3

2 Pétérù 3:1-8